Lati igbati ọsẹ mẹjọ ba kọja,
titi di opin iloyun,
"ọmọ enia ti ndagbasoke
ninu yi ni a npe ni fitọọsi,”
itumọ eyiti nse "ọmọ ti a ko i tii bi."
Ni akoko yi, eyiti a npe ni akoko fitọọsi,
gbogbo ẹya-ara ọmọ naa yio
dagbasoke sii, wọn yio si maa sisẹ.