Ọmọ inu oyun naa le di nkan mu,
o le mi ori rẹ siwaju ati sẹhin,
o le la ẹnu rẹ, o le gbe ahọn rẹ,
o le poS̩e, osi le na.
Isan-ara ti o wa ni oju, atẹlẹwọ,
ati atẹlẹsẹ ma nmọ ọ lara
bi a ba fi ọwọ kan wọn.
“Bi a ba rọra fi ọwọ kan gigise,”
ọmọ inu oyun yio rọ ibadi rẹ ati
orunkun rẹ yio si lẹ ọmọ-ika ẹsẹ rẹ pọ