Ọkan ọmọ naa, eyiti o pin si ọna mẹrin,
yio ti dagbasoke tan.
Ọkan naa yio maa mi ni iwọn igba ti o to
ẹẹmẹtadinlaadọsan laarin isẹju kan.
Agbara ti ọkan ọmọ naa ni,
eyiti a se akiyesi rẹ ni ọsẹ meje aabọ,
fihan wipe eyi fẹrẹ ba ti agbalagba enia dọgba.